........................................................Yemoja ati J3D,eyin Omo k'aaro Ojiire ti ede abinibi yin gbamuse !!!
Quote:
|
Originally Posted by Yemoja
here are some of mine:
Ta lo te eba fun e----- To ni t'obe o s'oro
.......................
ile olowo ti o n'tutu----
Igbeyin lo n'ye-----
Iya meji o kin je okobo-----
Ti tenikan o ba baje----- T'enikan o le dara
Tori warey ita----
iwofa lenu--- ohun to ba wu elenu lo ma fi enu eso
Ileke ma ja sile ... ma ja sita.. Ibi kan sa n'Ileke ma ja si
|
Quote:
|
Originally Posted by J3D
Peice of cake...at leasst some of 'em
1) Ologbon d'ori eja mu-- Omugo di iru e mu
2)Omode o mo Ogun------------- o n pe lefo
3) Eni Olorun da--- ko se f'arawe
4) Owo Omode ko to Pepe--- ti agbalagba o wo keregbe
5) Falaana gbo tie------- tara eni la n gbo
6) Aba ni Ikan nda--- ikan o le j'okuta
7) Osise (the worker) wa ninu Orun(sun)--- n'owo n'owo(or eni to ma naa) wa n'iboji
8) Apa l'ara.... Igunpa(elbow) ni yekan
9) A fi e J'Oba tan,O tun se awure............ Se O fe d'Olorun ni ?
10) A kii binu Ori... ka fi fila de Idi
|